Plays:19
Song DescriptionORIKI JESU. JE ANFANI LATI OGO ATI OLANLA JESU HAN
Lyrics
06.ORIKI JESU
Vox intro: -Ku abo, Ku abo: Oluwa Mi jesuKu abo 2X
Abiyamo Ni Jesu Olugbala aa- Oba To Wa Sinu Aiye
To Fi Ite Oogo Re Sile- Lati Wa Toju Enia
Ku abo Ku abo: Oluwa mi Jesu Ku abo
Lead:- Kaabo Arugbo Ojo,
Omo Alagogo Ajilu Gboin Gboin Ninu Tempili
Akanbi - Yaa Femi Mimo Bi,
Mimoyele Re 'Mo Oludumare;
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire: Akanbi o
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala,
Iwo Rewa Lenyan Oku Ori Ire Immanuel
Lead:- Iwo Renyan Omo Igbala,
Iwo Renyan Oku Ori Ire Akan Bio CHR:- Iwo Renyan O...
Lead:- Ngo Pee Ninu Ile : Pee Nirin Ajo:
Yo Dami Lohun : Kinsati Pee Lorukore
Lead:- Ku Abo Ku Abo: Oluwa Mi Jesu Ku Abo
Kaabo Arugbo Ojo,
Omo Alagogo Ajilu Gboin Gboin Ninu Tempili
Akanbi Yaa Femi Mimo Bi,
Mimoyele Re 'Mo Oludumare;
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire: AkanBio CHR:- Iwo Renyan O...
Lead:- Akobi Ninu Awon Oku Oba Ton Poro Iku,
Omo Ton Reni Lekun: Ajinde Ati Iye
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire Immanuel CHR:- Iwo Renyan O...
Lead:- Olori Awon Omo Ogun: Oba Awon Angeli,
Erujeje Leti Okun-Iwo Re lenyan Oku Ori Ire Akan Bio
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala, Iwo Rewa.....
Omo Alade Alafia: Ato-ba Jaiye :Eleburu Ike,
Akanbi M'Oludumare- Akanbi Omo Akosoro-
Omo Akoso Petiti Omo Oluogun Gbege Erii Ketekete
Mimoyele Re -Mo Oludumare e;
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire Immanuel CHR:- Iwo Renyan O...
Lead: - Towotowo Lan Reko, Lofelofe Lan Ra Gbala
Iwosan Kota Bii Tita Mo Ta Tan,
Gbogbo Eni Wao Lon Kore Dele Won
Olu-fejewe: jowo Feje Mimo Re Wemi,
Ki-nle Ri Gbala Okan
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire Emanuel...CHR:- Iwo Renyan O...
Lead:- Abiyamo Boja Boja Gboro,
Abiyamo Tin Gbani Lojo Eru
Abiyamo O - Lojo Eru
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire Immanuel
Irawo Owuro Omo Mary-Apa nla Tin Sole Aiye Ro
Abiyamo O - Lojo Ija;
Iwo Re Leyan Oku Ori Ire Immanuel
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala, Iwo Rewa....
Lead: Abiyamo Ni, Ni Jesu Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Egbe Omo Yin Wa Sodo Olugbala Wa.
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Ma Gbe Omo Mi Wa Sodo Olugbala Mi
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Oluwosan Ni Jesu Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Olu Dande Ni Jesu Omo Olorun Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala....2X
Abiyamo Ni Jesu Olugbala Oba To Wa Sinu Aiye
To Fi Ite Oogo Re Sile- Lati Wa Toju Enia
Ku abo Ku abo: Oluwa mi Jesu Ku abo
Lead:- Kaabo Arugbo Ojo,
Omo Alagogo Ajilu Gboin Gboin Ninu Tempili
Akanbi - Yaa Femi Mimo Bi,
Mimoyele Re 'Mo Oludumare;
Iwo Re lenyan Oku Ori Ire: Akanbi o
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala,
Iwo Rewa Lenyan Oku Ori Ire Immanuel
Chr: Iwo Renyan O, Oba Igbala....
Lead: Abiyamo Ni, Ni Jesu Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Egbe Omo Yin Wa Sodo Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Ma Gbe Omo Mi Wa Sodo Olugbala Mi
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Oluwosan Ni Jesu Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Olu Dande Ni Jesu Omo Olorun Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Lead: Abiyamo Ni, Ni Jesu Olugbala Wa
All: - Abiyamo Ni Jesu Olugbala
Repeat and end
Copyright © 2009 Joseph Awoyemi All rights reserved.
Song Length
9:31
Genres
Unique - Gospel, World - African
Tempo / Feel
Slow (71 - 90)
Lead Vocal
Mixed Vocals
Moods
In High Spirits, Exultant
Subject Matter
Gratitude, God
Era
Before 1600
Lyric Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Music Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Producer Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Publisher Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Performance Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Label Credits |
REV JOSEPH AWOYEMI |
|
Thanks for supporting JOSEPH ADEBAYO!
Please fill out the fields below, and we'll send you an email to verify your rating.
Email Address:
Name (first/last):
Comment to JOSEPH ADEBAYO (optional):
Cancel and close this window
Would you like to help JOSEPH ADEBAYO get heard by industry pros by buying them a song submission credit to Broadjam Music Licensing Opportunities?