JOSEPH ADEBAYO

JOSEPH ADEBAYO

facebook twitter
Unique - Gospel | COVENTRY, England, United Kingdom
Total Song Plays: 430   
Member Since: 2008
   Last Login: over 30 days ago

Profile    Songs    Photos    Connections    Endorsements   

Sign up for Broadjam today to follow JOSEPH ADEBAYO, and be notified when they upload new stuff or update their news!

Plays:

20

Song Description

MASE GBEKE LE ORISA. LATI RAN AWON ENIA LETI WIPE ORISA KOLE GBANI LA, LATI JE KI O DA AWON ENIA LOJU WIPE JESU NIKAN LO NI AGBARA LATI GBA ENIA LA

Lyrics


MASE GBEKELE ORISA:TITI AIYE MI TI JESU NI MIO
Lead:-Titi Aiye Mi Ti Jesu Ni Mio 2x
Titi Aiye Mi Ti Jesu Ni Mio 2x
Nko Ni Sina Lai, Nko Ni Sofo ninu Jesu ni Ngo Simi, Lojo Ologo,Pelu Awon Ayanfe Ni Gno Ma Dade O.

Lead:-Bori Mi Somi Ti Jesu Ni Mi O2x
Bori Mi Somi Ti Jesu Ni Mi O2X
Nko Ni Sika Lai
Nko Ni Dite -Ninu Jesu Ni Ngo Simi,
Lojo Ologo, Pelu Awon Ayanfe,
Ni Ngo ma Dade O

Lead: Emi Dupe Lowo Olorun Mi,
Eni Ti, O Ran, Jesu Sinu Aiye E
Lati Wa Ku Femi Omo Re: - L'oke Kalfari
O-Go: Iyin Ni F'olorun Mi,
O-Lupilese Igbagbomi;
Mo Wa Sibi Orisun Iye- K'emi Ba le la
Titi Aiye Mi Ti Jesu Ni Mi

Lead:Pupo Ninu Won Ton Wayo L'aiyeo
Ninu Egbe Ibi, Ninu Okunkun Aiye Ni.
Won Ke Si Baba, Won Pe Jesu L'oluwa,
Toba Di L'oru Won D'oso Won A d'Aje O;
Won Nwa Gbara, Ninu A- Fo-She,
Won Nwa Gbara Nin'ogungun Ika
Bori Mi So Mi Nko Ni Soogun Lailai
Titi Aiye Mi Ti Jesu Ni Mi
(Jesu Yi Ma Dun)

ALL:- Titi Aiye Mi Ti Jesu Ni Mio 2x
Nko Ni Sina Lai, Nko Ni Sofo ninu Jesu ni Ngo Simi, Lojo Ologo,Pelu Awon Ayanfe Ni Gno Ma Dade O.

All:- Kosorisa; Orisa Kan kole Gbani La, Ko S'orisa-

Lead:- Je-Su Lo To Ni Gba
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole Gbani ....
Lead:- Ademolade Lo Toni Gba
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole .......

Lead:- Igi Oko Ko To Nii Gba
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole .......
(Mase gbekele won)

Lead:-Eda Enia Ko To Ni Gba
All:- Kosorisa;....(Mase gbekele won)

Lead:- Egbe Oso Ko Toni Gba
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole ........

Lead:- Egbe Aje Ko Toni Gba
All:- Kosorisa;....(Mase gbekele won)

Lead:- Oloogun Ko Toni Gba
All:- Kosorisa;...(Mase gbekele won)

Lead:- Oloselu ko to nii gba
All:- Kosorisa;....(Mase gbekele won)

Lead:- Egbe Okunkun ko to nii gba
All:- Kosorisa;....(Mase gbekele won)

Lead:-Je-Su Lo To Ni Gba (Omo Olorun Alaaye)
All:- Kororisa; Orisa Kan ........

Lead:- Ademolade Lo Toni Gba
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole .......

Lead:- Je-Su Lo To Ni Gba (Omo Olorun Alaaye)
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole Gbani La, Ko S'orisa

Lead:Jesu Lo To Ni Gba (Abiyami Boja Gborogboro)
All:- Kosorisa; Orisa Kan Kole ......
Copyright © 2009 Joseph Awoyemi. All Rights Reserved

Song Length
5:39
Genres
Unique - Gospel, World - African
Tempo / Feel
Medium Slow (91 - 110)
Lead Vocal
Mixed Vocals
Moods
Content, In High Spirits

Subject Matter
Determination, Courage


Era
2000 and later

Lyric Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Music Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Producer Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Publisher Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Performance Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Label Credits REV JOSEPH AWOYEMI