JOSEPH ADEBAYO

JOSEPH ADEBAYO

facebook twitter
Unique - Gospel | COVENTRY, England, United Kingdom
Total Song Plays: 430   
Member Since: 2008
   Last Login: over 30 days ago

Profile    Songs    Photos    Connections    Endorsements   

Sign up for Broadjam today to follow JOSEPH ADEBAYO, and be notified when they upload new stuff or update their news!

Plays:

37

Song Description

JE KA RELE: ORIN FUN GBOGBO IDILE. LATI GBA GBOGBO IDILE LATI GBA JESU SINU AIYE WON

Lyrics

JE KA RELE OLORUN: - mo ko orin yifun itona idile onigbagbo
LEAD: Nile Oluwa Ni Ngo Ma Gbe O:Nibe Ni Mo- Ti Ri Ye
Se Bi Nibe Nimo Ti Pade Jesu ;Ti Mo Ti Domo Igbala Titi Aiye
Fara Mo: Emi Faramo Jesu Faramo
Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo
ALL:-Fara Mo:Emi Faramo Jesu Faramo
LEAD: - Je Ka Rele Olorun Eleda Wa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Je Ka Rele: Lo Josin Oluwa Wa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Inu Min Dun lati Lole Oluwa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Alaaye Niyo Ma Yin: Olorun Wa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Mako Omo Ati Aya Mi Mora ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Mako Ile Ati Ebi Mi Mora ALL:- Fara Mo.....
Int2x
Gbogbo Ojo Ti Mo Ni Lo Ninu Aiye
Ninu Ile Re lemi yo Ma Gbe
Ile Olorun Lemi yo Ma Gbe O
Tori Mo Dom'Olorun Alaaye (m'Olorun Alaaye)
Tori ati fi eje Oluwa Rami
Emi Ti Di Ibo Folorun Mi

Fara Mo :Emi Faramo Jesu Faramo ALL:- Fara Mo.....
Je Ka Rele: Olorun Eleda Wa ALL:- Fara Mo.....
Irawo Owuro:: Omo Mary Apanla Tin Saiye Ro ALL:- Fara Mo.....
Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:- Fara Mo.....

Chr:- Oya Oya 2x Oya Wa Ami Rele O Gbe Gbe Igbe Soko
Oya Wa Ami Rele O, Kukute Ki Gbe Sodan
Lead:- Josefu Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Amosi Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Olusegun Ka Re Le All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Deborah Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Felicia Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Samueli Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Gebureli Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:-Benjameni Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O

Chr:- Oya Oya 2x Oya Wa Ami Rele O Gbe Gbe Igbe Soko
Oya Wa Ami Rele O, Kukute Ki Gbe Sodan2x
Lead:- Dafidi Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Johanu Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Comforti Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Joysi Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:- Maria Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:-Corneliu Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:-Kristeni Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O
Lead:-Peteru Ka Rele All:- Ori Oye Kii Sun Ta O

Chr:- Oya Oya 2x Oya Wa Ami Rele O Gbe Gbe Igbe Soko.....2x

LEAD: So Kale Oluwa Sokale2x Edumare Gbemi Dele,
Ile, Ile Mi Lorun, Edumare Gbemi Dele O
All: - Fara Mo Ngo fara mo jesu faramo
LEAD: - Nibiti Ko Si Kokoro Tabi Ipaara.
LEAD: - Nibiti Ole Kii Tii Runle. All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Gbogbo Ojo Toti Lo Ninu Aiye Oti To All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Aiye Titun Ma Lo Yeo Ore Mio All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Gbogbo Ayida Aiye Ki Yo Bao Mo All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Lodo Eniti Ko Si Ibanuje Tabi Aro All: - Fara Mo Emi .....

LEAD: - Lodo Eni Tao Gbade Iye Tii Kii Baje All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Lodo Eni Ti Ao Yayo: - Ayeraye All: - Fara Mo Emi .....
LEAD: - Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo All: - Fara Mo Emi .....

LEAD:Nile Oluwa Ni Ngo Ma Gbe O:Nibe Ni Mo- Ti Ri Ye
Se Bi Nibe Nimo Ti Pade Jesu ;Ti Mo Ti :Domo Igbala Titi Aiye
Fara Mo: Emi Faramo Jesu Faramo
LEAD:Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:-Fara Mo:Emi Faramo Jesu Faramo
LEAD: - Je Ka Rele Olorun Eleda Wa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Inu Min Dun lati Lole Oluwa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Alaaye Niyo Ma Yin: Olorun Wa ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Mako Omo Ati Aya Mi Mora ALL:- Fara Mo.....
LEAD: Mako Ile Ati Ebi Mi Mora ALL:- Fara Mo.....
LEAD:Irawo Owuro:: Omo Mary Apanla Tin Sole Aaiye Ro ALL:- Fara Mo.....
LEAD:Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:- Fara Mo.....
LEAD:Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:- Fara Mo.....
LEAD:Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:- Fara Mo.....
LEAD:Eji Eji Gbogbo Okan To Sun Lo ALL:- Fara Mo.....

REPEAT AND END
Copyright © 2009 Joseph Awoyemi. All rights reserved.

Song Length
11:37
Genres
Unique - Gospel, World - Reggae/Carribean


Era
2000 and later

Lyric Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Music Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Producer Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Publisher Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Performance Credits REV JOSEPH AWOYEMI
Label Credits REV JOSEPH AWOYEMI